A6-B
Àtẹ: Àwọn Wòlíì àti Àwọn Ọba Ilẹ̀ Júdà àti Ísírẹ́lì (Apá Kejì)
Àwọn Ọba Ìjọba Gúúsù (A ti ń bá a bọ̀)
777 Ṣ.S.K.
Jótámù: 16 ọdún
762
Áhásì: 16 ọdún
746
Hẹsikáyà: 29 ọdún
716
Mánásè: 55 ọdún
661
Ámọ́nì: 2 ọdún
659
Jòsáyà: 31 ọdún
628
Jèhóáhásì: oṣù 3
Jèhóákímù: 11 ọdún
618
Jèhóákínì: oṣù 3, ọjọ́ 10
617
Sedekáyà: 11 ọdún
607
Nebukadinésárì ọba Bábílónì àtàwọn èèyàn rẹ̀ ṣígun wá, wọ́n sì pa Jerúsálẹ́mù àti tẹ́ńpìlì run. Wọ́n mú Sedekáyà, ọba ìlà ìdílé Dáfídì tó jẹ kẹ́yìn ní ayé kúrò lórí ìtẹ́
Àwọn Ọba Ìjọba Àríwá (A ti ń bá a bọ̀)
n. 803 B.C.E.
Sekaráyà: àkọsílẹ̀ fi hàn pé oṣù 6 péré lo fi jọba
Sekaráyà bẹ̀rẹ̀ sí í jọba lọ́nà kan ṣáá, àmọ́ ẹ̀rí fi hàn pé nǹkan bí ọdún 792 ni ìjọba náà tó di tirẹ̀
n. 791
Ṣálúmù: oṣù 1
Ménáhémù: 10 ọdún
n. 780
Pekaháyà: 2 ọdún
n. 778
Pékà: 20 ọdún
n. 758
Hóṣéà: 9 ọdún láti n. 748
n. 748
Ó jọ pé ìṣàkóso Hóṣéà wá fìdí múlẹ̀ dáadáa tàbí pé ó rí ìtìlẹ́yìn gbà látọ̀dọ̀ ọba Ásíríà, Tigilati-pílésà Kẹta ní nǹkan bí ọdún 748
740
Ásíríà ṣẹ́gun Samáríà, ó tẹ Ísírẹ́lì lórí ba; ìjọba ẹ̀yà mẹ́wàá àríwá Ísírẹ́lì dópin
-
Orúkọ Àwọn Wòlíì
-
Àìsáyà
-
Míkà
-
Sefanáyà
-
Jeremáyà
-
Náhúmù
-
Hábákúkù
-
Dáníẹ́lì
-
Ìsíkíẹ́lì
-
Ọbadáyà
-
Hósíà