A7-F
Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù—Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tí Jésù Tún Ṣe ní Ìlà Oòrùn Jọ́dánì
ÀKÓKÒ |
IBI |
ÌṢẸ̀LẸ̀ |
MÁTÍÙ |
MÁÀKÙ |
LÚÙKÙ |
JÒHÁNÙ |
---|---|---|---|---|---|---|
32, lẹ́yìn Àjọyọ̀ Ìyàsímímọ́ |
Bẹ́tánì ní òdìkejì |
Jọ́dánì Ó lọ síbi tí Jòhánù ti ń ṣèrìbọmi fún àwọn èèyàn; ọ̀pọ̀ gba Jésù gbọ́ |
||||
Pèríà |
Ó rọ àwọn èèyàn pé kí wọ́n gba ẹnu ọ̀nà tóóró wọlé; ó kédàárò lórí Jerúsálẹ́mù |
|||||
Ó rọ àwọn èèyàn pé kí wọ́n gba ẹnu ọ̀nà tóóró wọlé; ó kédàárò lórí Jerúsálẹ́mù |
||||||
Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ ní Pèríà |
Ó kọ́ni ní ìwà ìrẹ̀lẹ̀; àwọn àpèjúwe: ibi tó lọ́lá jù àtàwọn tí wọ́n pè tó ń ṣàwáwí |
|||||
Ronú lórí ohun tó máa náni láti di ọmọ ẹ̀yìn |
||||||
Àwọn àpèjúwe: àgùntàn tó sọ nù, ẹyọ owó tó sọ nù, ọmọkùnrin tó sọ nù |
||||||
Àwọn àpèjúwe: ìríjú aláìṣòdodo, ọkùnrin ọlọ́rọ̀ àti Lásárù |
||||||
Ẹ̀kọ́ nípa ìkọsẹ̀, ìdáríjì àti ìgbàgbọ́ |
||||||
Bẹ́tánì |
Lásárù kú, ó sì jíǹde |
|||||
Jerúsálẹ́mù; Éfúrémù |
Wọ́n gbìmọ̀ pọ̀ láti pa Jésù; ó kúrò níbẹ̀ |
|||||
Samáríà; Gálílì |
Ó wo adẹ́tẹ̀ mẹ́wàá sàn; ó sọ bí Ìjọba Ọlọ́run ṣe máa dé |
|||||
Samáríà tàbí Gálílì |
Àwọn àpèjúwe: opó tí kò yéé bẹ̀bẹ̀, Farisí àti agbowó orí |
|||||
Pèríà |
Ó kọ́ni nípa ìgbéyàwó àti ìkọ̀sílẹ̀ |
|||||
Ó súre fún àwọn ọmọdé |
||||||
Ìbéèrè ọkùnrin ọlọ́rọ̀ náà; àpèjúwe nípa àwọn òṣìṣẹ́ ọgbà àjàrà àti owó iṣẹ́ wọn tó dọ́gba |
||||||
Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ ní Pèríà |
Ó sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀ nígbà kẹta |
|||||
Jémíìsì àti Jòhánù fẹ́ gba ipò nínú Ìjọba Ọlọ́run |
||||||
Jẹ́ríkò |
Jẹ́ríkò Ó gba ibẹ̀ kọjá, ó la ojú ọkùnrin méjì tó jẹ́ afọ́jú; ó lọ sọ́dọ̀ Sákéù; àpèjúwe mínà mẹ́wàá |