January 4-10
LÉFÍTÍKÙ 18-19
Orin 122 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Má Jẹ́ Kí Ohunkóhun Ba Ìwà Mímọ́ Rẹ Jẹ́”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Le 19:9, 10—Kí ló fi hàn pé Ọlọ́run gba tàwọn tálákà rò nínú Òfin tó fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì? (w06 6/15 22 ¶11)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Le 18:1-15 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: Àdúrà—Sm 65:2. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì jíròrò ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 3)
Àsọyé: (5 min.) w02 2/1 29—Àkòrí: Ṣé Àwa Kristẹni Ṣì Ń Ṣègbọràn sí Òfin Mósè Tó Ka Ìgbéyàwó Láàárín Ìbátan Léèwọ̀? (th ẹ̀kọ́ 7)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Dáàbò Bo Ọmọ Rẹ: (5 min.) Alàgbà ni kó sọ àsọyé yìí. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Kó o sì sọ ẹ̀kọ́ tá a rí kọ́.—Owe 22:3.
“Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Rí I Pé Ẹ̀ Ń Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Kọ́ Ilé Tó Máa Wà Pẹ́ Títí—Dáàbò Bo Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ “Ohun Búburú.”
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 2 ¶28-31, àpótí 2A àti 2B
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 96 àti Àdúrà