Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Bó O Ṣe Lè Ṣe Orúkọ Rere fún Ara Ẹ

Bó O Ṣe Lè Ṣe Orúkọ Rere fún Ara Ẹ

Rúùtù ò mọ tara ẹ̀ nìkan, ó ṣe tán láti ran àwọn míì lọ́wọ́ (Rut 3:10; w12 10/1 22 ¶4)

“Obìnrin àtàtà” làwọn èèyàn mọ Rúùtù sí (Rut 3:11; w12 10/1 23 ¶1)

Jèhófà bù kún Rúùtù torí pé ó ní ìwà tó dáa (Rut 4:11-13; w12 10/1 24 ¶2)

Kọ àwọn ìwà dáadáa tó o máa fẹ́ káwọn èèyàn mọ̀ mọ́ ẹ.