MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ TẸ̀ Ẹ̣́ Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ Nígbà Àkọ́kọ́ Ìbéèrè: Tá a bá wà nínú ìṣòro, kí ló jẹ́ ká mọ̀ pé Ọlọ́run kọ́ ló ń fìyà jẹ wá? Bíbélì: Jem 1:13 Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí nìdí tá a fi ń jìyà? WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́: T-34 Ìpadàbẹ̀wò Ìbéèrè: Kí nìdí tá a fi ń jìyà? Bíbélì: 1Jo 5:19 Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ló jẹ́ ká mọ̀ pé inú Ọlọ́run ò dùn sí ìyà tó ń jẹ wá? WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́: T-33 Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ Lóde Ìwàásù ní July-August 2023. Yorùbá Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ Lóde Ìwàásù ní July-August 2023. https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202023265/univ/art/202023265_univ_sqr_xl.jpg mwb23 July ojú ìwé 16