Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Báwo la ṣe lè mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú?
Bíbélì: Ais 46:10
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Àwọn àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì wo là ń rí tó ń ṣẹ lónìí?
○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Àwọn àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì wo là ń rí tó ń ṣẹ lónìí?
Bíbélì: Mt 24:6, 7, 14
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ló máa ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn tí “òpin” bá ti dé?
○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ
Ìbéèrè: Kí ló máa ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn tí “òpin” bá ti dé?
Bíbélì: Iṣi 21:4
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Ibo ni àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì yìí ti máa ṣẹ?