April 4-10
1 SÁMÚẸ́LÌ 20-22
Orin 90 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Bó O Ṣe Lè Jẹ́ Ọ̀rẹ́ Gidi”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
1Sa 21:12, 13—Kí la rí kọ́ nínú ohun tí Dáfídì ṣe? (w05 3/15 24 ¶5)
Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Sa 22:1-11 (th ẹ̀kọ́ 5)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìpadàbẹ̀wò: (2 min.) Pa dà lọ sọ́dọ̀ ẹnì kan tó nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ rẹ, tó sì gba ìwé ìkésíni. (th ẹ̀kọ́ 6)
Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Lẹ́yìn tí Ìrántí Ikú Kristi parí, fọgbọ́n bẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ pẹ̀lú ẹnì kan tó o pè. Kó o wá dáhùn ìbéèrè tó béèrè nípa bẹ́ ẹ ṣe ṣèpàdé náà. (th ẹ̀kọ́ 12)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 04 kókó 3 (th ẹ̀kọ́ 20)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Àwọn Wo Lò Ń Bá Ṣọ̀rẹ́ Lórí Ìkànnì?”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Máa Fọgbọ́n Lo Ìkànnì Àjọlò.
Ẹ Kí Àwọn Tá A Pè Káàbọ̀: (5 min.) Àsọyé tí alábòójútó iṣẹ́ ìsìn máa sọ, látinú Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti oṣù March 2016. Jẹ́ kí ìjọ mọ ibi tẹ́ ẹ pín ìwé ìkésíni dé. Gba àwọn ará níyànjú pé kí wọ́n wo ìtòlẹ́sẹẹsẹ Bíbélì kíkà tó wà fún Ìrántí Ikú Kristi tó wà lójú ìwé 10 àti 11, kí wọ́n sì múra ọkàn wọn sílẹ̀ fún Ìrántí Ikú Kristi. (Ẹsr 7:10) Jẹ́ káwọn ará mọ ètò tó wà nílẹ̀ nípa bẹ́ ẹ ṣe máa ṣe Ìrántí Ikú Kristi.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr Àkópọ̀ Àwọn Àtúnṣe Tó Bá Òye Wa, ìbéèrè 1-4
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 95 àti Àdúrà