December 13-19
ÀWỌN ONÍDÀÁJỌ́ 8-9
Orin 125 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ó Sàn Kéèyàn Lẹ́mìí Ìrẹ̀lẹ̀ Ju Kó Jẹ́ Agbéraga”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Ond 8:27—Ṣé Gídíónì jọ́sìn éfódì tó ṣe? (it-1 753 ¶1)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ond 8:28–9:6 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 9)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún onílé ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì, kó o sì bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 20)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lffi ẹ̀kọ́ 02 kókó 4 (th ẹ̀kọ́ 13)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (5 min.) Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù December.
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (10 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 17 ¶9-14
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 22 àti Àdúrà