December 20-26
ÀWỌN ONÍDÀÁJỌ́ 10-12
Orin 127 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ẹni Tẹ̀mí ni Jẹ́fútà”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Ond 11:1—Báwo la ṣe mọ̀ pé Jẹ́fútà kì í ṣe ọmọ àlè? (it-2 26)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ond 10:1-18 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Bẹ̀rẹ̀ ìjíròrò pẹ̀lú ìwé àṣàrò kúkúrú náà Irú Ìwé Wo Ni Bíbélì? (th ẹ̀kọ́ 1)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún onílé ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 4)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lffi ẹ̀kọ́ 02 kókó 5 (th ẹ̀kọ́ 3)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Àtikékeré Ni Mo Ti Ya Ara Mi Sí Mímọ́ fún Jèhófà: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Báwo ni fídíò yìí ṣe jẹ́ ká rí i pé ó yẹ: ká máa dá àwọn míì lẹ́kọ̀ọ́? kéèyàn ya ara ẹ̀ sí mímọ́ nígbà tó ṣì wà lọ́dọ̀ọ́? kéèyàn máa yọ̀ǹda ara ẹ̀ láti ṣe púpọ̀ sí i nínú ètò Ọlọ́run?
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 17 ¶15-21
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 55 àti Àdúrà