December 27, 2021–January 2, 2022
ÀWỌN ONÍDÀÁJỌ́ 13-14
Orin 134 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ohun Táwọn Òbí Lè Rí Kọ́ Látinú Ohun Tí Mánóà àti Ìyàwó Rẹ̀ Ṣe”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Ond 14:2, 3—Kí nìdí tí Sámúsìn fi sọ pé obìnrin ará Filísínì yẹn “lẹni tó yẹ” òun? (w05 3/15 26 ¶1)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ond 14:5-20 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
“Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Ran Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́wọ́ Láti Máa Dá Kẹ́kọ̀ọ́”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Ran Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́wọ́ Láti Máa Dá Kẹ́kọ̀ọ́.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lffi kókó pàtàkì ní ẹ̀kọ́ 02, kí lo rí kọ́? àti ohun tó yẹ kó o ṣe (th ẹ̀kọ́ 17)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 18 ¶1-8 àti fídíò ohun tó wà ní orí 18
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 148 àti Àdúrà