November 1-7
JÓṢÚÀ 18-19
Orin 12 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Jèhófà Fọgbọ́n Pín Ilẹ̀ Fáwọn Èèyàn Rẹ̀”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Joṣ 18:1-3—Kí ló lè fà á táwọn ọmọ Ísírẹ́lì ò fi tètè lọ gba ilẹ̀ tó kù lápá ìwọ̀ oòrùn Jọ́dánì? (it-1 359 ¶5)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Joṣ 18:1-14 (th ẹ̀kọ́ 2)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: Ìròyìn Ayọ̀—Sm 37:10, 11. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì jíròrò ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.
Nígbà Àkọ́kọ́: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún onílé ní Ilé Ìṣọ́ No. 2 2021. (th ẹ̀kọ́ 1)
Nígbà Àkọ́kọ́: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 11)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“A Dúpẹ́ Lọ́wọ́ Jèhófà Torí Ìfẹ́ Tẹ́ Ẹ̀ Ń Fi Hàn”: (15 min.) Ìjíròrò. Alàgbà ni kó ṣe iṣẹ́ yìí. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò À Ń “Dúpẹ́ Lọ́wọ́ Ọlọ́run Nígbà Gbogbo Nítorí Yín.” Mẹ́nu ba ọ̀kan tàbí méjì nínú àwọn àpilẹ̀kọ́ tó wà lórí ìkànnì jw.org ní abala “Bá A Ṣe Ń Ná Owó Tẹ́ Ẹ Fi Ń Ṣètọrẹ.”
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 15 ¶15-17 àti àpótí 15A
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 122 àti Àdúrà