November 29–December 5, 2021
ÀWỌN ONÍDÀÁJỌ́ 4-5
Orin 137 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Jèhófà Gba Àwọn Èèyàn Rẹ̀ Là Nípasẹ̀ Àwọn Obìnrin Méjì”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Ond 5:20—Báwo làwọn ìràwọ̀ ṣe jà látọ̀run nítorí Bárákì? (w05 1/15 25 ¶5)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ond 4:1-16 (th ẹ̀kọ́ 10)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún onílé ní Ilé Ìṣọ́ No. 2 2021. (th ẹ̀kọ́ 1)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún onílé ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 4)
Àsọyé: (5 min.) w06 3/1 28-29—Àkòrí: Kí Nìtumọ̀ Ohun Tí Bíbélì Sọ Pé Káwọn “Obìnrin Máa Dákẹ́ Nínú Ìjọ”?—1Kọ 14:34. (th ẹ̀kọ́ 14)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Báwo Làwọn Arábìnrin Ṣe Lè Ṣe Púpọ̀ Sí I Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà?”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò “Àwọn Obìnrin Tó Ń Ṣiṣẹ́ Kára Nínú Olúwa.”
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 16 ¶14-20 àti àpótí 16B
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 27 àti Àdúrà