October 18-24
JÓṢÚÀ 12-14
Orin 69 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Máa Fi Gbogbo Ọkàn Rẹ Tẹ̀ Lé Jèhófà”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Joṣ 12:7-24 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fi ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 6)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún onílé ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì kó o sì bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ní ẹ̀kọ́ 01. (th ẹ̀kọ́ 20)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lffi ẹ̀kọ́ 01 kókó 5 (th ẹ̀kọ́ 18)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)
“Jẹ́ Kí Jèhófà Máa Wà Níwájú Rẹ Nígbà Gbogbo”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Máa Ṣiṣẹ́ Jèhófà Tọkàntọkàn.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr apá 4, orí 15 ¶1-7 àti fídíò ohun tó wà ní orí 15
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 32 àti Àdúrà