September 6-12
DIUTARÓNÓMÌ 33-34
Orin 150 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Jẹ́ Kí Jèhófà Fi ‘Ọwọ́ Ayérayé’ Rẹ̀ Dáàbò Bò Ẹ́”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Di 34:6—Kí nìdí tí Jèhófà ò fi jẹ́ káwọn ọmọ Ísírẹ́lì mọ sàréè Mósè? (it-2 439 ¶3)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Di 33:1-17 (th ẹ̀kọ́ 10)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: Bíbélì—2Ti 3:16, 17. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì jíròrò ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 1)
Nígbà Àkọ́kọ́: (5 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún onílé ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì kó o sì bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 3)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Máa Lo Ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Ohun Tó O Máa Gbádùn Nínú Ẹ̀kọ́ Bíbélì Rẹ. Tí àkókò bá wà, mẹ́nu kan díẹ̀ lára àwọn nǹkan tó wà nínú ìwé tuntun náà. Rọ àwọn ará pé kí wọ́n kẹ́kọ̀ọ́ ìwé náà lẹ́nìkọ̀ọ̀kan tàbí nígbà Ìjọsìn Ìdílé.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 13 ¶7-14 àti àpótí 13A
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 18 àti Àdúrà