ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Ohun Mẹ́ta Táá Jẹ́ Ká Ní Ọgbọ́n, Kó sì Ṣe Wá Láǹfààní
Máa kíyè sí àwọn ohun tí Ọlọ́run dá (Job 12:7-9; w09 4/15 6 ¶17)
Mú àwọn tí òtítọ́ jinlẹ̀ nínú wọn lọ́rẹ̀ẹ́ (Job 12:12; w21.06 10-11 ¶10-12)
Kẹ́kọ̀ọ́ nípa àwọn ìlànà Ọlọ́run, kó o sì máa fi wọ́n sílò nígbèésí ayé rẹ (Job 12:16; it-2 1190 ¶2)
BI ARA RẸ PÉ, ‘Bí mo ṣe ń wà pẹ̀lú àwọn Kristẹni tí òtítọ́ jinlẹ̀ nínú wọn, kí ni mo ti rí kọ́ lára wọn?’