ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ April 2024
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti June 10–July 7, 2024 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 14
“Ẹ Jẹ́ Ká Tẹ̀ Síwájú, Ká Dàgbà Nípa Tẹ̀mí”
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní June 10-16, 2024.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 15
Túbọ̀ Fọkàn Tán Jèhófà àti Ètò Ẹ̀
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní June 17-23, 2024.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 16
Bí Iṣẹ́ Ìwàásù Ṣe Lè Túbọ̀ Máa Fún Ẹ Láyọ̀
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní June 24-30, 2024.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 17
Má Kúrò Nínú Párádísè Tẹ̀mí Láé
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní July 1-7, 2024.
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Jèhófà Ràn Mí Lọ́wọ́ Láti Ṣàṣeyọrí, Láìka Kùdìẹ̀-Kudiẹ Mi Sí
Arákùnrin Erkki Mäkelä sọ bí Jèhófà ṣe yanjú àwọn ìṣòro òun nígbà tóun ń ṣiṣẹ́ ìsìn alákòókò kíkún àtìgbà tóun ń ṣiṣẹ́ míṣọ́nnárì lágbègbè Kòlóńbíà, níbi táwọn ẹgbẹ́ kan ti ń ṣọ̀tẹ̀ sí ìjọba.
Ǹjẹ́ O Mọ̀?
Kí nìdí táwọn tí kì í ṣe ọmọ Ísírẹ́lì fi wà lára ọmọ ogun Ọba Dáfídì?