ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ December 2020
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti February 1-28, 2021 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
Ṣé ohun tí àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù sọ nínú 1 Kọ́ríńtì 15:29 ni pé àwọn Kristẹni kan ṣèrìbọmi nítorí àwọn òkú?
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
Òwe 24:16 sọ pé: “Olódodo lè ṣubú ní ìgbà méje, á sì tún dìde.” Ṣé ohun tí ẹsẹ yìí ń sọ ni pé èèyàn lè máa dẹ́ṣẹ̀ léraléra kí Ọlọ́run sì máa dárí jì í?