ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ February 2024
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti April 8–May 5, 2024 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 7
Ohun Tá A Kọ́ Lára Àwọn Násírì
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní April 22-28, 2024.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 8
Máa Ṣe Ohun Tí Jèhófà Bá Sọ
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní April 29–May 5, 2024.
Máa Láyọ̀ Bó O Ṣe Ń Fi Sùúrù Dúró De Jèhófà
Ọ̀pọ̀ ni nǹkan ti tojú sú bí wọ́n ṣe ń dúró de Jèhófà pé kó dáhùn àdúrà àwọn. Kí ló máa jẹ́ ká lè fi sùúrù dúró de Jèhófà, ká sì máa láyọ̀ bá a ṣe ń dúró dè é?
Àwọn Arákùnrin Méjì Tó Ṣẹ̀ṣẹ̀ Di Ara Ìgbìmọ̀ Olùdarí
Ní Wednesday, January 18, 2023, wọ́n gbé ìfilọ̀ pàtàkì kan sórí jw.org pé Arákùnrin Gage Fleegle àti Arákùnrin Jeffrey Winder ti di ara Ìgbìmọ̀ Olùdarí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà.
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
Kí ni Bíbélì sọ nípa agbára tí Jèhófà ní láti mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú?
Ǹjẹ́ O Mọ̀?
Ẹ jẹ́ ká wo nǹkan mẹ́ta tó mú káwọn òǹkọ̀wé yẹn tún àwọn ọ̀rọ̀ kan sọ léraléra.
OHUN TÓ O LÈ FI KẸ́KỌ̀Ọ́