ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ January 2016
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti February 29 sí April 3, 2016 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
“Ẹ Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Ará Tí Ẹ Ní Máa Bá A Lọ”!
Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ wa ti ọdún 2016 lè ràn wá lọ́wọ́ láti múra sílẹ̀ de àwọn ohun tó máa tó ṣẹlẹ̀.
Jẹ́ Kí ‘Ẹ̀bùn Ọ̀fẹ́ Aláìṣeé-Ṣàpèjúwe’ Ti Ọlọ́run Mú Ẹ Lọ́ranyàn
Báwo ni ìfẹ́ tí Ọlọ́run ní sí wa ṣe ń mú ká máa tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Jésù pẹ́kípẹ́kí, báwo ló sì ṣe ń mú ká máa fìfẹ́ hàn sáwọn ará wa ká sì máa dárí ji àwọn tó ṣẹ̀ wá?
Ẹ̀mí Ń Jẹ́rìí Pẹ̀lú Ẹ̀mí Wa
Kí ló túmọ̀ sí pé kí Ọlọ́run fẹ̀mí yan ẹnì kan? Báwo ni Ọlọ́run ṣe ń fẹ̀mí yan èèyàn?
“Àwa Yóò Bá Yín Lọ”
Kí ló yẹ ká máa fi sọ́kàn nípa àwọn 144,000?
À Ń Láyọ̀ Bá A Ṣe Ń Bá Ọlọ́run Ṣiṣẹ́
Báwo ni bíbá Ọlọ́run ṣiṣẹ́ ṣe ń mú ká láyọ̀, báwo ló sì ṣe ń dáàbò bò àjọṣe tá a ní pẹ̀lú rẹ̀?