Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ṣé O Ti Béèrè Rí?

Ṣé O Ti Béèrè Rí?
  • Kí ló dé tí ìṣòro fi pọ̀ gan-an láyé?

  • Báwo lo ṣe máa rí ọgbọ́n tó o lè fi kojú ìṣòro ìgbésí ayé?

  • Ṣé Ọlọ́run kà ẹ́ sí pàtàkì?​—1 Pétérù 5:​6, 7.

  • Báwo lo ṣe lè mọ̀ nípa Ọlọ́run àti ohun tó fẹ́?

Àìmọye èèyàn ti rí ìdáhùn tó tẹ́ wọn lọ́rùn sáwọn ìbéèrè yìí nígbà tí wọ́n kẹ́kọ̀ọ́ nínú Ìwé Mímọ́. Ìwọ náà lè ṣe bẹ́ẹ̀.

Tó o bá fẹ́ mọ̀ sí i, jọ̀ọ́ sọ fún àwọn tó ṣe ìwé ìròyìn yìí pé kí wọ́n fún ẹ ní ìwé náà, Ìgbàgbọ́ Òdodo Ló Máa Mú Kó O Ní Ayọ̀. Ọ̀fẹ́ ni. O sì lè kà á lórí ìkànnì www.dan124.com.