Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
◼ Ṣé Ọlọ́run á tìtorí pé o jẹ́ olóòótọ́ sọ ẹ́ di ọlọ́rọ̀? Wo ojú ìwé 4.
◼ Ṣé owó ni orísun ayọ̀ tòótọ́? Wo ojú ìwé 9.
◼ Ṣó pọn dandan kéèyàn gbà pé Ádámù àti Éfà ti gbé ayé rí? Wo ojú ìwé 12.
◼ Ṣó dáa kéèyàn máa gbẹ̀san àbí kò dáa? Kí lèrò ẹ? Wo ojú ìwé 20.
◼ Àwọn nǹkan ṣíṣeyebíye wo lo lè rí ní erékùṣù tó tóbi jù lọ ní Amẹ́ríkà Àárín? Wo ojú ìwé 25.