Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
Kí nìdí tó fi jẹ́ pé ẹ̀dá èèyàn nìkan ló ń gbàdúrà? WO OJÚ ÌWÉ 3.
Ǹjẹ́ Ọlọ́run máa ń fetí sí àdúrà wa tó sì ń dáhùn wọn? WO OJÚ ÌWÉ 11.
Kí ni ìyàtọ̀ tó wà láàárín iṣẹ́ ìyanu tí Jésù ṣe àti èyí táwọn oníṣẹ́ ìyanu ń ṣe lónìí? WO OJÚ ÌWÉ 13.
Báwo ni Bíbélì ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ láti borí èrò òdì? WO OJÚ ÌWÉ 19.
Ṣé ẹ̀mí mímọ́ jẹ́ ẹnì kan? WO OJÚ ÌWÉ 26.