Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
Kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì pé kéèyàn ní ẹ̀mí ìmoore? WO OJÚ ÌWÉ 6.
Kí lo lè sọ láti fi tu ọ̀rẹ́ tàbí èèyàn rẹ kan tó ń ṣọ̀fọ̀ nínú? WO OJÚ ÌWÉ 9 SÍ 11.
Ǹjẹ́ àwọn áńgẹ́lì ń wá ire wa? WO OJÚ ÌWÉ 16.
Ǹjẹ́ Bíbélì sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ìdásílẹ̀ orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì òde òní? WO OJÚ ÌWÉ 27 SÍ 29.
Ǹjẹ́ Jésù fẹ́ káwọn ọmọlẹ́yìn òun dara pọ̀ mọ́ ẹ̀sìn kan? WO OJÚ ÌWÉ 31.
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 32]
Todd Bolen/Bible Places.com