Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
Ṣé àjálù kan tó lé kenkà ni Amágẹ́dọ́nì?
Kí nìdí tí Ọlọ́run ìfẹ́ yóò fi pa àwọn èèyàn nígbà ogun Amágẹ́dọ́nì?
Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ pàtàkì mẹ́ta wo ni Bíbélì sọ pé ó máa ṣẹlẹ̀ láìpẹ́?
Kí ló ran ọ̀mùtí kan lọ́wọ́ láti yí ìgbésí ayé rẹ̀ pa dà?
Ṣé ayé yìí máa pa run?