Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
Kí nìdí tí Ọlọ́run fi fàyè gba kí ìyà máa jẹ àwa èèyàn?
WO OJÚ ÌWÉ 8 SÍ 9.
Kí nìdí tí aráyé fi nílò ìjọba kan tó máa ṣàkóso gbogbo ayé?
WO OJÚ ÌWÉ 16 SÍ 17.
Kí lo lè ṣe tí gbèsè ò fi ní máa gbé ọ lọ́kàn sókè?
WO OJÚ ÌWÉ 21.
Ṣé ẹni tó bá lóun ní ìgbàgbọ́ kàn ń tan ara rẹ̀ jẹ ni?
WO OJÚ ÌWÉ 23.