ILÉ ÌṢỌ́ March 2013 | Àǹfààní Tí Àjíǹde Jésù Ṣe fún Wa

Ṣé àjíǹde Jésù ṣe ṣàǹfààní kankan fún wa lónìí?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ṣé Òótọ́ Ni Pé Jésù Jíǹde?

Níwọ̀n bí àjíǹde Jésù ti jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára ẹ̀kọ́ Bíbélì, ó yẹ ká wádìí bóyá ó ṣẹlẹ̀ lóòótọ́.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Àjíǹde Jésù Máa Jẹ́ Ká Ní Ìyè Àìnípẹ̀kun!

Ìwọ rò ó wò ná, kéèyàn wà láàyè títí láé láìsí ìrora, ìyà àti ọ̀fọ̀ kankan.

Ǹjẹ́ O Mọ̀?

Báwo ni àwọn Júù ọgọ́rùn-⁠ún ọdún kìíní ṣe ń múra òkú sílẹ̀ kí wọ́n tó lọ sin ín? Ṣé bí àwọn Júù ṣe máa ń sìnkú ni wọ́n ṣe sin Jésù?

ÀWỌN ÒǸKÀWÉ WA BÉÈRÈ PÉ

Ṣé Ọ̀run Ni Jésù Sọ Pé Aṣebi Tó Wà Lẹ́gbẹ̀ẹ́ Òun Yóò Lọ?

Jésù ṣèlérí fún aṣebi yẹn pé: “Ìwọ yóò wà pẹ̀lú mi ní Párádísè.” Kí ló ní lọ́kàn?

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

“Mo Rí I, Ṣùgbọ́n Kò Yé Mi”

Olivier ní ìṣòro àrà ọ̀tọ̀ torí pé ó jẹ́ adití. Wo bí Jèhófà ṣe ràn án lọ́wọ́.

SÚN MỌ́ ỌLỌ́RUN

“Èwo Ni Èkínní Nínú Gbogbo Òfin?”

A lè fi gbólóhùn kan péré ṣe àkópọ̀ gbogbo ohun tí Ọlọ́run fẹ́ ká máa ṣe.

KỌ ỌMỌ RẸ

Pétérù Parọ́, Ananíà Náà Parọ́​—⁠Ẹ̀kọ́ Wo Ni Èyí Kọ́ Wa?

Wo ìdí tí ọ̀kan fi rí ìdáríjì gbà, àmọ́ tí èkejì kò rí gbà.

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Kí nìdí tí Bíbélì fi pe Jésù ní “Ọmọ Ọlọ́run” àti “àkọ́bí nínú gbogbo ìṣẹ̀dá”?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Ṣé Kristẹni Làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Jọ̀wọ́ ṣàgbéyẹ̀wò bí a ṣe yàtọ̀ sí àwọn míì tí wọ́n ń pè ní Kristẹni.