Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ 2020
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ “Ẹ Máa Yọ̀ Nígbà Gbogbo”! ti Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti ọdún 2020.
Friday
A gbé ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Friday ka Fílípì 4:4 tó ní: “Ẹ máa yọ̀ nígbà gbogbo nínú Olúwa. Lẹ́ẹ̀kan sí i, mo sọ pé, Ẹ máa yọ̀!”
Saturday
A gbé ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Saturday ka Sáàmù 105:3 tó ní: “Ẹ máa fi orúkọ mímọ́ rẹ̀ yangàn. Kí ọkàn àwọn tó ń wá Jèhófà máa yọ̀.”
Sunday
A gbé ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Sunday ka Sáàmù 37:4 tó ní: “Jẹ́ kí inú rẹ máa dùn jọjọ nínú Jèhófà,yóò sì fún ọ ní àwọn ohun tí ọkàn rẹ fẹ́.”
Ohun Tá A Fẹ́ Kí Àwọn Tó Wá sí Àpéjọ Yìí Mọ̀
Àwọn ìsọfúnni tó máa ṣe àwọn tó wá láǹfààní.