Saturday
“Ẹ máa fi orúkọ mímọ́ rẹ̀ yangàn. Kí ọkàn àwọn tó ń wá Jèhófà máa yọ̀”—Sáàmù 105:3
ÀÁRỌ̀
9:20 Fídíò Orin
9:30 Orin 53 àti Àdúrà
9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Túbọ̀ Já Fáfá
• Máa Lo Ìbéèrè (Jémíìsì 1:19)
• Jẹ́ Kí Àwọn Èèyàn Rí Agbára Tí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ní (Hébérù 4:12)
• Máa Fi Àpèjúwe Ṣàlàyé Kókó Pàtàkì (Mátíù 13:34, 35)
• Máa Lo Ìtara Tó O Bá Ń Kọ́ni (Róòmù 12:11)
• Máa Fọ̀rọ̀ Ro Ara Ẹ Wò (1 Tẹsalóníkà 2:7, 8)
• Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Rẹ Wọni Lọ́kàn (Òwe 3:1)
10:50 Orin 58 àti Ìfilọ̀
11:00 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Máa Lo Àwọn Nǹkan Tí Jèhófà Pèsè
• Àwọn Ohun Èlò Ìwádìí (1 Kọ́ríńtì 3:9; 2 Tímótì 3:16, 17)
• Àwọn Ará (Róòmù 16:3, 4; 1 Pétérù 5:9)
• Àdúrà (Sáàmù 127:1)
11:45 ÌRÌBỌMI: Bí Ìrìbọmi Ṣe Máa Jẹ́ Kó O Túbọ̀ Láyọ̀ (Òwe 11:24; Ìfihàn 4:11)
12:15 Orin 79 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀SÁN
1:35 Fídíò Orin
1:45 Orin 76
1:50 Bí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Ṣe Ń Fún Àwọn Ará Wa Láyọ̀ ní . . .
• Áfíríkà
• Éṣíà
• Yúróòpù
• Amẹ́ríkà ti Àríwá
• Oceania
• Amẹ́ríkà ti Gúúsù
2:35 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ran Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́wọ́ Láti . . .
• Máa Dá Kẹ́kọ̀ọ́ (Mátíù 5:3; Jòhánù 13:17)
• Máa Wá Sípàdé (Sáàmù 65:4)
• Yẹra fún Ẹgbẹ́ Búburú (Òwe 13:20)
• Jáwọ́ Nínú Ìwà Àìmọ́ (Éfésù 4:22-24)
• Ní Àjọṣe Tímọ́tímọ́ Pẹ̀lú Jèhófà (1 Jòhánù 4:8, 19)
3:30 Orin 110 àti Ìfilọ̀
3:40 FÍÌMÙ: Nehemáyà: “Ìdùnnú Jèhófà Ni Ibi Ààbò Yín”—Apá Kìíní (Nehemáyà 1:1–6:19)
4:15 Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn ti Ìsinsìnyí Ń Múra Wa Sílẹ̀ De ti Ayé Tuntun (Àìsáyà 11:9; Ìṣe 24:15)
4:50 Orin 140 àti Àdúrà Ìparí