Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ àti Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Lára àwọn ọ̀rọ̀ Jésù táwọn èèyàn mọ̀ jù lọ ni èyí tó sọ lórí òkè kan nítòsí ìlú Kápánáúmù, tó wà létí Òkun Gálílì. Ọ̀pọ̀ èèyàn mọ ọ̀rọ̀ náà sí Ìwàásù Orí Òkè, ó sì wà ní orí 5 sí 7 nínú ìwé Mátíù tó wà nínú Bíbélì. Ìwé yìí á jẹ́ kó o mọ àwọn ọ̀rọ̀ yẹn, kí ìwọ náà lè jàǹfààní látinú ọgbọ́n Jésù.
ORÍ 5
ORÍ 6
ORÍ 7