Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé
Ẹlẹ́dàá fẹ́ tọ́ wa sọ́nà, ó fẹ́ dáàbò bò wá, ó sì fẹ́ bù kún wa.
Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú
Torí pé Ọlọ́run nífẹ̀ẹ́ aráyé, ó ń kọ́ wa bá a ṣe lè gbé ayé lọ́nà tó dára jù lọ.
Báwo La Ṣe Lè Tẹ́tí sí Ọlọ́run?
Ó yẹ ká mọ ohun tí a máa ṣe àti ẹni tó lè ràn wá lọ́wọ́.
Ta Ni Ọlọ́run Tòótọ́?
A lè mọ orúkọ rẹ̀, ká sì mọ díẹ̀ lára àwọn ànímọ́ rẹ̀.
Báwo Ni Ìgbésí Ayé Ṣe Rí Nínú Ọgbà Édẹ́nì?
Ìwé àkọ́kọ́ nínú Bíbélì ṣàlàyé bó ṣe rí.
Kí Ló Ṣẹlẹ̀ Lẹ́yìn Tí Wọ́n Tẹ́tí sí Sátánì?
Nǹkan burúkú bẹ̀rẹ̀ sí í ṣẹlẹ̀.
Nígbà Ìkún Omi, Àwọn Wo Ló Tẹ́tí sí Ọlọ́run? Àwọn Wo Ni Kò Tẹ́tí sí I?
Báwo ni ìwà àwọn èèyàn ṣe yàtọ̀ síra?
Kí Ni Ìkún Omi Náà Kọ́ Wa?
Kì í ṣe ìtàn àtijọ́ kan lásán.
Ta Ni Jésù?
Kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì ká mọ̀ ọ́n?
Kí Ni Ikú Jésù Mú Kó Ṣeé Ṣe fún Ọ?
Ó máa mú ká rí àwọn ìbùkún àgbàyanu gbà.
Ìgbà Wo Ni Ayé Máa Di Párádísè?
Bíbélì sọ àwọn ohun tó máa ṣẹlẹ̀ tó bá ti sún mọ́lé.
Àwọn Ìbùkún Wo Ni Àwọn Tó Bá Tẹ́tí sí Ọlọ́run Máa Rí Gbà?
Ìwọ náà á fẹ́ gbádùn àwọn ìbùkún yẹn.
Ṣé Jèhófà Máa Ń Tẹ́tí Gbọ́ Wa?
Àwọn nǹkan wo lo lè bá a sọ?
Báwo Ni Ìdílé Rẹ Ṣe Lè Ní Ayọ̀?
Ẹni tó dá ìdílé sílẹ̀ ló lè fún wa nímọ̀ràn tó wúlò jù.
Kí La Lè Ṣe Láti Mú Inú Ọlọ́run Dùn?
Àwọn ohun kan wà tó kórìíra, àwọn ohun kan sì wà tó nífẹ̀ẹ́.
Báwo Lo Ṣe Lè Fi Hàn Pé O Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà?
Tó o bá pinnu lọ́kàn ẹ pé wàá jẹ́ adúróṣinṣin, ó máa hàn nínú àwọn ìpinnu tó o bá ń ṣe.