Ìgbésí Ayé àti Ìwà Rere
Ìgbeyàwó àti Ìdílé
Ǹjẹ́ Bíbélì Lè Ràn Mí Lọ́wọ́ Láti Ní Ìdílé Aláyọ̀?
Ìmọ̀ràn ọlọ́gbọ́n láti inú Bíbélì ti ran ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn lọ́kùnrin àti lóbìnrin lọ́wọ́ láti ní ìdílé aláyọ̀.
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ìgbéyàwó?
Ìlànà Bíbélì lè ran tọkọtaya lọ́wọ́ kí wọ́n máa bàa ní ìṣòro tàbí kí wọ́n lè borí rẹ̀.
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Gbígbé Pọ̀ Láìṣègbéyàwó?
Àwọn ìtọ́ni Ọlọ́run jẹ́ ká mọ bá a ṣe lè ní ìdílé aláyọ̀, kò sì ìgbà tí ìlànà rẹ̀ kì í ṣe àwọn tó bá ń tẹ̀ lé e láǹfààní.
Ǹjẹ́ Bíbélì Sọ̀rọ̀ Nípa Ìgbéyàwó Láàárín Ọkùnrin àti Ọkùnrin Tàbí Láàárín Obìnrin àti Obìnrin?
Ẹni tó dá ìgbéyàwó sílẹ̀ ló yẹ kò mọ̀ béèyàn ṣe lè ní ìgbéyàwó tó wà pẹ́ títí lọ, tó sì láyọ̀.
Ǹjẹ́ Bíbélì Fàyè Gba Ìkọ̀sílẹ̀?
Kọ́ nípa ohun tí Ọlọ́run fàyè gbà àti ohun tó kórìíra.
Ǹjẹ́ Ọlọ́run Fọwọ́ Sí I Pé Kí Ọkùnrin Fẹ́ Ju Ìyàwó Kan Lọ?
Ṣé Ọlọ́run ló dá àṣà kí ọkùnrin máa fẹ́ ju ìyàwó kan lọ sílẹ̀? Kẹ́kọ̀ọ́ nípa ohun tí Bíbélì sọ nípa kí ọkùnrin fẹ́ ju ìyàwó kan lọ.
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ìgbéyàwó Àwọn Tí Kì í Ṣe Ẹ̀yà Kan Náà?
Wo àwọn ìlànà Bíbélì tó ní í ṣe pẹ̀lú ọ̀rọ̀ ẹ̀yà àti ìgbéyàwó.
Kí Ló Túmọ̀ Sí Láti ‘Bọlá fún Baba àti Ìyá Rẹ’?
Ó máa yà ẹ́ lẹ́nu láti mọ àwọn nǹkan tí àṣẹ yẹn kò túmọ̀ sí pé ká ṣe.
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Bí A Ṣe Lè Tọ́jú Àwọn Òbí Wa Tó Ti Dàgbà?
Bíbélì sọ àpẹẹrẹ àwọn ọkùnrin àti obìnrin tó nígbàgbọ́ tó ṣe bẹ́ẹ̀. Ó tún jẹ́ ká rí àwọn ìmọ̀ràn tó gbéṣẹ́ tó lè ṣèrànwọ́ fún àwọn tó ń tọ́jú àwọn àgbàlagbà.
Ìbálòpọ̀
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ìbẹ́yà-Kan-Náà-Lòpọ̀?
Irú ojú wo ni Ọlọ́run fi ń wo ìbẹ́yà-kan-náà-lòpọ̀? Ǹjẹ́ ó ṣe é ṣe kéèyàn mú inú Ọlọ́run dùn tó bá ń wù ú láti bá ọkùnrin tàbí obìnrin bíi tirẹ̀ lò pọ̀?
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Àwòrán Oníhòòhò àti Fífi Ohun Tó Ń Mú Ọkàn Fà Sí Ìṣekúṣe Ránṣẹ́ Lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì?
Àwọn eré ìnàjú tó n gbé ìbálòpọ̀ lárugẹ tí wọ́pọ̀ gan-an báyìí. Ṣé ó yẹ ká máa lọ́wọ́ nínú rẹ̀ torí pé gbogbo èèyàn ló mọ̀ nípa rẹ̀?
Ǹjẹ́ Bíbélì Ta Ko Ìbálòpọ̀?
Ṣé ẹ̀ṣẹ̀ ni téèyàn bá ní ìbálòpọ̀?
Ṣé Ó Burú Kí Kristẹni Fètò Sọ́mọ Bíbí?
Bí tọkọtaya bá fẹ́ fètò sọ́mọ bíbí, ǹjẹ́ òfin wà tó yẹ kí wọ́n gbé yẹ̀ wò?
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Dáàbò Bo Ara Mi Lọ́wọ́ Àwọn Tó Ń Fi Ìṣekúṣe Lọ̀ Mí?
Àwọn ìmọ̀ràn méje tó gbéṣẹ́ tá a gbé ka àwọn ọ̀rọ̀ ọgbọ́n tó wà nínú Bíbélì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó o lè borí àwọn tó ń fi ìṣekúṣe lọ̀ ẹ́.
Báwo Ni Àwọn Òbí Ṣe Lè Kọ́ Àwọn Ọmọ Wọn Nípa Ìbálòpọ̀?
Bíbélì ni àwọn ìlànà tó wúlò táá jẹ́ kó o lè bá ọmọ rẹ sọ̀rọ̀ nípa ìbálòpọ̀ kó o sì tún lè dáàbò bo wọ́n lọ́wọ́ àwọn tó ń bọ́mọdé ṣèṣekúṣe.
Ohun Tó Wù Ẹ́
Ṣé Kristẹni Lè Gba Ìtọ́jú Lọ́dọ̀ Àwọn Dókítà?
Ǹjẹ́ irú ìtọ́jú tá a pinnu láti gbà ṣe pàtàkì lójú Ọlọ́run?
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Gbígba Ẹ̀jẹ̀ Sára?
Àṣẹ Ọlọ́run tó wà nínú Bíbélì ni pé ká ‘ta kété sí ẹ̀jẹ̀.’ Báwo ni àṣẹ yìí ṣe kàn wá lóde òní?
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ìṣẹ́yún?
Ìgbà wo ni ìwàláàyè ẹ̀dá èèyàn bẹ̀rẹ̀? Ṣé Ọlọ́run máa dárí ji ẹni tó bá ṣẹ́yún?
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Fínfín Àmì sí Ara?
Ǹjẹ́ ó máa ń wù ọ́ kó o fín ara? Àwọn ìlànà Bíbélì wo ló yẹ kó o ronú lé lórí?
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ṣíṣe Ara Lóge?
Ṣé Bíbélì sọ pé ó burú téèyàn bá lo àwọn ohun ìṣaralóge láti túnra ṣe?
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ọtí? Ṣé Ẹ̀ṣẹ̀ Ni Kí Èèyàn Máa Mu Ọtí?
Bíbélì sọ ohun tó dára nípa wáìnì àti ọtí.
Ṣé Ẹ̀ṣẹ̀ Ni Kí Èèyàn Mu Sìgá tàbí Igbó?
Tó bá jẹ́ pé Bíbélì ò sọ̀rọ̀ nípa sìgá mímu, báwo la ṣe lè dáhùn ìbéèrè yìí?
Ṣé Ẹ̀ṣẹ̀ Ni Tẹ́tẹ́ Títa?
Bíbélì ò ṣe kúlẹ̀kúlẹ̀ àlàyé nípa tẹ́tẹ́ títa, báwo la ṣe wá lè mọ irú ojú tí Ọlọ́run fi ń wò ó?
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Òmìnira Láti Yan Ohun Tó Wuni? Ṣé Ọlọ́run Ló Ń Darí Gbogbo Nǹkan?
Ọ̀pọ̀ èèyàn gbà gbọ́ pé kádàrá ló ń darí ìgbésí ayé àwọn. Ǹjẹ́ ohun tá a bá yan láti ṣe ló máa ń pinnu bóyá a ó ṣàṣeyọrí?
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Ṣe Ìpinnu Tó Mọ́gbọ́n Dání?
Ohun mẹ́fà tí Bíbélì sọ pé o lè ṣe kó o lè ní ọgbọ́n àti òye.
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Fífúnni?
Báwo ni Ọlọ́run ṣe fẹ́ ká máa fúnni?