Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àdúrà

Kí Nìdí To Fi Yẹ Kó O Máa Gbàdúrà?

Ṣé Ọlọ́run Á Gbọ́ Àdúrà Mi?

Bóyá Ọlọ́run máa gbọ́ àdúrà tó o bá gbà tàbí kò ní gbọ́ kù sí ọwọ́ rẹ.

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí O Máa Gbàdúrà?

Ọlọ́run lè dáhùn àdúrà wa láìjẹ́ pé ó ṣe iṣẹ́ ìyanu.

Ṣé Ọlọ́run Ń Gbọ́ Àdúrà Wa?

Bíbélì jẹ́ kó dá wa lójú pé tá a bá gbàdúrà lọ́nà tó tọ́, Ọlọ́run máa gbọ́ àdúrà wa.

Àǹfààní Tó O Máa Rí Nínú—Àdúrà

Tó o bá ń gbàdúrà déédéé, àǹfààní wo ló máa ṣe fún ẹ?

“Ẹ Máa Kó Gbogbo Àníyàn Yín Lọ Sọ́dọ̀ Rẹ̀”

Ṣé òótọ́ ni pé a lè gbàdúrà sí Ọlọ́run nípa àwọn nǹkan tó ń kó ìdààmú ọkàn bá wa? Táwọn tó ní ìdààmú ọkàn bá ń gbàdúrà, àǹfààní wo nìyẹn máa ṣe wọ́n?

Bó O Ṣe Lè Gbàdúrà

Bó O Ṣe Lè Gbàdúrà Kí Ọlọ́run Sì Gbọ́

O lè gbàdúrà sí Ọlọ́run níbikíbi àti nígbàkigbà. Ó lè gbàdúrà sókè tàbí kó o gbà á sínú. Kódà, Jésù kọ́ wa ní ohun tá a lè sọ nínú àdúrà wa.

Ṣé Àdúrà Olúwa Ni Àdúrà Tó Dáa Jù Láti Gbà?

Ṣé Àdúrà Olúwa nìkan ni Ọlọ́run máa ń gbọ́?

Kí Ni Mo Lè Gbàdúrà Fún?

Mọ bí dídáhùn àdúrà nípa ọ̀rọ̀ ara ẹni ò ṣe lè ṣòro fún Ọlọ́run.

Máa Gbàdúrà Kó O Lè Rí Ojú Rere Ọlọ́run

Báwo la ṣe lè gbàdúrà lọ́nà tí Ọlọ́run á fi gbọ́ àdúrà wa?

Ṣé Gbogbo Àdúrà Ni Ọlọ́run Máa Ń Gbọ́?

Tó bá jẹ́ pé tara ẹ nìkan lò ń gbà ládùúrà ńkọ́? Tí ọkọ kan bá ń fìyà jẹ ìyàwó ẹ̀, tó sì wá ń gbàdúrà fún ìbùkún Ọlọ́run ńkọ́?

Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Kì Í Fi Í Gbọ́ Àwọn Àdúrà Kan?

Kà nípa irú àwọn àdúrà tí Ọlọ́run kì í gbọ́ àti irú àwọn ẹni tí Ọlọ́run kì í gbọ́ tiwọn.

Kí Nìdí Tí Mo Fi Gbọ́dọ̀ Gbàdúrà Lórúkọ Jésù?

Ṣàgbéyẹ̀wò nípa bí gbígbàdúrà lórúkọ Jésù ṣe ń bọlá fún Ọlọ́run tó sì ń fi hàn pé à ń bọ̀wọ̀ fún Jésù.

Se Jesu Lo Ye Ka Maa Gbadura Si?

Jesu funra re dahun ibeere yii.

Ṣó Yẹ Kí N Máa Gbàdúrà sí Àwọn Ẹni Mímọ́?

Ka ohun tí Bíbélì sọ nípa ẹni tó yẹ ká gbàdúrà sí.

Gbàdúrà Nígbà Gbogbo

Fídíò tó ṣeé wà jáde yìí máa jẹ́ káwọn ọmọdé mọ ìgbà tí wọ́n lè gbàdúrà sí Jèhófà àti ibi tí wọ́n ti lè gbàdúrà.