Bí Ìgbàgbọ́ Rẹ Nínú Ọlọ́run Ṣe Lè Lágbára
Kí Nìdí To Fi Yẹ Kó O Gba Ọlọ́run Gbọ́?
Ǹjẹ́ Ọlọ́run Wà?
Bíbélì fún wa ní ẹ̀rí márùn-ún tó jẹ́ ká mọ̀ pé lóòótọ́ ni Ọlọ́run wà.
Ṣé Ọlọ́run Wà Lóòótọ́?
Wàá rí àwọn ẹ̀rí tó jẹ́ kó dá wa lójú pé Ọlọ́run wà.
Ìdí Tá A Fi Gbà Gbọ́ Pé . . . Ọlọ́run Wà
Àwọn ohun tó díjú lára ìṣẹ̀dá jẹ́ kí ọ̀jọ̀gbọ́n kan gbà pé Ọlọ́run wà.
Bí O Ṣe Lè Mọ Ọlọ́run
Ṣé Ọlọ́run ní Orúkọ?
Ọlọ́run ní ọ̀pọ̀ orúkọ oyè, lára rẹ̀ ni Olódùmarè, Ẹlẹ́dàá, àti Olúwa. Fídíò yìí sọ orúkọ Ọlọ́run gangan èyí tó fara hàn ní ibi tó lé ni ẹgbẹ̀rún méje [7,000] nínú Bíbélì.
Kí Ni Orúkọ Ọlọ́run?
Ṣé o mọ̀ pé Ọlọ́run ní orúkọ kan tó jẹ́ kó yàtọ̀ gedegbe?
Báwo Lo Ṣe Lè Mọ Ọlọ́run?
Ohun méje tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó o lè di ọ̀rẹ́ Ọlọ́run.
Àwọn Ohun Tí Jèhófà Dá Fi Hàn Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Wa—Ara Èèyàn
Àwọn ẹ̀yà ara wa àti bá a ṣe ń rántí nǹkan kọ́ wa ní ẹ̀kọ́ pàtàkì kan.
Àwọn Wòlíì Jẹ́ Ká Mọ Ọlọ́run
Àwọn wòlíì mẹ́ta kan wà tí wọ́n jẹ́ ka mọ Ọlọ́run àti bá a ṣe lè gba ìbùkún rẹ̀.
Ǹjẹ́ A Lè Mọ Ọlọ́run?
Àwọn nǹkan tí a kò mọ̀ nípa Ọlọ́run lè mú kó o túbọ̀ sún mọ́ Ọlọ́run sí i.
Báwo La Ṣe Lè Rí Ọlọ́run?
Kọ́ bí o ṣe lè lo “ojú ọkàn-àyà rẹ.”
Ohun Tó Jẹ́ Òtítọ́ Nípa Ọlọ́run àti Kristi
Ìyàtọ̀ wo ló wà láàárín Jèhófà Ọlọ́run àti Jésù Kristi?
Irú Ẹni Wo Ni Ọlọ́run?
Kí ni àwọn ànímọ́ Ọlọ́run tó ta yọ jù?
Ṣé Ọlọ́run Ń Kíyè Sí Ẹ?
Kí ló jẹ́ ká mọ̀ pé Ọlọ́run mọ̀ wá dáadáa?
Ṣé Ọlọ́run Mọ Bí Nǹkan Ṣe Máa Ń Rí Lára Wa?
Bíbélì jẹ́ kó dá wa lójú pé Ọlọ́run mọ̀ wá dáadáa, ọ̀rọ̀ wa yé e, ó sì máa ń dùn ún tá a bá ní ìṣòro.
Bí Ìgbàgbọ́ Ṣe Ṣe Pàtàkì Tó
Ìdí Tá A Fi Nílò Ọlọ́run
Kọ́ nípa bí a ṣe lè láyọ̀ kí ìgbésí ayé wa sì ládùn tí a bá sún mọ́ Ọlọ́run.
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ìgbàgbọ́?
Bíbélì sọ pé ‘láìsí ìgbàgbọ́ kò ṣeé ṣe láti wù Ọlọ́run dáadáa.’ Kí ni ìgbàgbọ́? Báwo lo ṣe lè ní ìgbàgbọ́?
Ṣé Ẹni Tó Bá Lóun Ní Ìgbàgbọ́ Kàn Ń Tan Ara Rẹ̀ Jẹ Ni?
Bíbélì kò sọ pé ká kàn máa gba gbogbo nǹkan gbọ́, kàkà bẹ́ẹ̀, ó rọ̀ wá pé ká lo agbára ìmọnúurò wa, ká sì gbé àwọn ẹ̀rí tó wà yẹ̀ wò.
Bibeli Dahun Gbogbo Ibeere Mi
Igbagbo ti Mayli Gündel ni ninu Olorun mehe nigba ti baba re ku. Bawo ni igbagbo re se soji to fi wa ni ibale okan?
Ọ̀rọ̀ Ẹ̀sìn Yọ Lọ́kàn Mi
Ó wu Tom pé kó nígbàgbọ́ nínú Ọlọ́run, ṣùgbọ́n ó bà á nínú jẹ́ láti rí i pé irọ́ làwọn onísìn fi ń kọ́ni. Báwo ni ohun tó kọ́ nínú Bíbélì ṣe jẹ́ kó ní ìrètí?
Àwọn Ìpèníjà Ìgbàgbọ́
Ṣé Ẹ̀sìn Ti Wá Di Òwò Tó Ń Mówó Rẹpẹtẹ Wọlé?
Àwọn ṣọ́ọ̀ṣì kan wà tí ọ̀pọ̀ àwọn tó ń lọ síbẹ̀ jẹ́ aláìní, ṣùgbọ́n tí àwọn pásítọ̀ wọn ní ọrọ̀ rẹpẹtẹ.
Ǹjẹ́ Ó Tọ́ Ká Máa Bi Ọlọ́run Ní Ìbéèrè?
Ibo la ti lè rí ìdáhùn tó ń tẹ́ni lọ́rùn sí àwọn ìbéèrè nípa ìgbésí ayé. Ṣé a lè bi Ọlọ́run?
Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Gbà Pé Ká Máa Jìyà?
Ọ̀pọ̀ èèyàn ló máa ń béèrè pé kí ló fà á tí ìkórìíra àti ìyà fi pọ̀ láyé. Bíbélì dáhùn ìbéèrè yìí lọ́nà tó tẹ́ni lọ́rùn tó sì tuni nínú.
Kí Nìdí Tí Àwọn Èèyàn Fi Ń Sọ Pé Ìkà Ni Ọlọ́run?
Àwọn èèyàn kan rò pé ìkà ni Ọlọ́run tàbí pé ọ̀rọ̀ wa kò ká a lára? Kí ni Bíbélì sọ?
Sún Mọ́ Ọlọ́run
Báwo Lo Ṣe Lè Sún Mọ́ Ọlọ́run?
Kẹ́kọ̀ọ́ kó o lè mọ̀ bóyá gbogbo àdúrà ni Ọlọ́run máa ń gbọ́, mọ bó ṣe yẹ ká máa gbàdúrà àti ohun míì tó lè mú kó o sún mọ́ Ọlọ́run.
Kí Nìdí Tí Ẹ̀bùn Yìí Fi Ṣe Iyebíye Gan-an?
Àwọn nǹkan wo ló lè mú kí ẹ̀bùn kan ṣeyebíye ju ẹ̀bùn mí ì lọ? Tá a bá ronú lórí kókó yìí, ó máa jẹ́ ká túbọ̀ lè mọ rírì ìràpadà náà.
Ohun Tó Dáa àti Ohun Tí Kò Dáa: Bíbélì Ni Afinimọ̀nà Tó Dájú
Kí ló máa jẹ́ kó dá ẹ lójú pé àwọn ìmọ̀ràn inú Bíbélì ṣeé gbára lé?
Ǹjẹ́ A Lè Mú Inú Ọlọ́run Dùn?
A lè rí ìdáhùn nínú bí Jóòbù, Lọ́ọ̀tì àti Dáfídì ṣe gbé ìgbé ayé wọn, àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta ló ṣe àṣìṣe ńlá.
Wàá Jàǹfààní Tó O Bá Mọ̀ Pé Ọlọ́run Bìkítà Nípa Rẹ
Ìwé Mímọ́ ràn wá lọ́wọ́ láti túbọ̀ ní ìgbàgbọ́ nínú ìlérí Ọlọ́run pé ọ̀la ń bọ̀ wá dára.