Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ

Dáfídì Jẹ́ Onígboyà

Torí pé ọmọkùnrin kan tó ń jẹ́ Dáfídì gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, ó nígboyà, ó sì ṣẹ́gun òmìrán kan. Ka ọ̀rọ̀ inú àwòrán ìtàn Bíbélì yìí lórí ìkànnì wa tàbí kó o tẹ̀ ẹ́ jáde.