Fìfẹ́ Wá Wọn Lọ
Báwo lo ṣe lè wá àwọn míì lọ kó o lè ràn wọ́n lọ́wọ́?
O Tún Lè Wo
DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ
Wá Wọn Lọ (Orin 150)
Oríṣiríṣi ọ̀nà ló wà tó o lè fi wá àwọn míì lọ kó o lè ràn wọ́n lọ́wọ́.
OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ
Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Eré
Lo àwọn eré yìí láti ṣàlàyé ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ọ̀wọ́ fídíò Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà, kó o sì jíròrò àwọn ẹ̀kọ́ inú ẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ.
Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ
Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé
Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.