Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Máa Fara Dà Á Tí Wọ́n Bá Rẹ́ Ẹ Jẹ

Máa Fara Dà Á Tí Wọ́n Bá Rẹ́ Ẹ Jẹ

Àwọn èèyàn máa ń rẹ́ wa jẹ́ nígbà míì. Kí ló yẹ ká ṣe tí wọ́n bá rẹ́ wa jẹ?

O Tún Lè Wo

DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Máa Fara Dà Á Tí Wọ́n Bá Rẹ́ Ẹ Jẹ

Báwo ni àpẹẹrẹ Jósẹ́fù tó wà nínú Bíbélì ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ láti fara dà á tí wọ́n bá rẹ́ wa jẹ?

OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ

Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—Eré

Lo àwọn eré yìí láti ṣàlàyé ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ọ̀wọ́ fídíò Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà, kó o sì jíròrò àwọn ẹ̀kọ́ inú ẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ.

Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ

Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé

Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.