Sọ Bí Àwọn Àwòrán Yìí Ṣe Yàtọ̀ Síra: Eré Àpéjọ Àgbègbè
Ǹjẹ́ o rí ìyàtọ̀ kankan nínú àwọn àwòrán méjì yìí? Èwo nínú àwọn àwòrán yìí ló sọ bó ṣe yẹ kó o máa ṣe tó o bá wà ní àpéjọ àgbègbè?
O Tún Lè Wo
DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ
Ṣíṣiṣẹ́ Pa Pọ̀ ní Ìṣọ̀kan (Orin 101)
Wo ìṣọ̀kan tó wà láàárín ẹgbẹ́ ará wa tó kárí ayé.
OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ
Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Eré
Lo àwọn eré yìí láti ṣàlàyé ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ọ̀wọ́ fídíò Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà, kó o sì jíròrò àwọn ẹ̀kọ́ inú ẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ.
Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ
Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé
Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.