Ẹ̀kọ́ 33: Múnú Jèhófà Dùn
Báwo lo ṣe lè fara wé Jésù kó o sì múnú Jèhófà dùn?
O Tún Lè Wo
ERÉ DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ
Múnú Jèhófà Dùn
Tá a bá ń ṣègbọràn sí Jèhófà, tá a sì ń ṣe àwọn ìpinnu tó mọ́gbọ́n dání, à ń múnú rẹ̀ dùn nìyẹn.
Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ
Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé
Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.