Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ

Fáráò (1513 Ṣ.S.K.)

Wa Káàdì Eré Bíbélì yìí jáde, kó o sì kẹ́kọ̀ọ́ lára Ọba Íjíbítì tó ṣàìgbọràn sí ohun tí Jèhófà sọ. Tẹ̀ ẹ́, gé e, ká a sí méjì, kó o sì tọ́jú rẹ̀.