Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

Art àti Zanna Capers: Jèhófà Ló Bá Wa Tún Ìdílé Wa Tò

Art àti Zanna Capers: Jèhófà Ló Bá Wa Tún Ìdílé Wa Tò

Tọkọtaya kan kọ ara wọn sílẹ̀ torí pé wọ́n ní àwọn ìṣòro tí wọn ò lè dá yanjú. Àmọ́ nígbà tí wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, tí wọ́n sì ń tẹ̀ lé ìlànà Ọlọ́run, wọ́n yanjú aáwọ̀ náà, wọ́n sì pa dà fẹ́ra. Ní báyìí, wọ́n ń láyọ̀ nínú ìdílé wọn.