Ìsọfúnni Ṣókí—Philippines
- 113,964,000—Iye àwọn èèyàn
- 253,876—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 3,552—Iye àwọn ìjọ
- 464—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
LÁTINÚ ÀPAMỌ́ WA
Wọ́n Ń Sin Jèhófà Nìṣó Láìka Ìṣòro Àìlówó Lọ́wọ́ Sí
Nǹkan nira gan-an fáwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà lórílẹ̀-èdè Philippines láàárín ọdún 1970 sí 1989. Ka àpilẹ̀kọ yìí kó o lè rí bí àpẹẹrẹ wọn ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ táwọn nǹkan àìròtẹ́lẹ̀ bá ṣẹlẹ̀ sí wa.
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Mo Di “Ohun Gbogbo fún Ènìyàn Gbogbo”
Àwọn iṣẹ́ tí Denton Hopkinson ti ṣe nínú ìjọsìn Jèhófà látọdún yìí wá ti jẹ́ kó rí bí Jèhófà ṣe ń fa àwọn èèyàn láti ibi gbogbo sínú ètò rẹ̀.
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú ní Philippines.
Kẹ́kọ̀ọ́ nípa ohun tó mú kí àwọn kan fi iṣẹ́ tí wọ́n ń ṣe sílẹ̀, kí wọ́n ta àwọn ohun ìní wọn, tí wọ́n sì lọ sí àdádó ní orílẹ̀-èdè Philippines