Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Romania

  • Bucharest, Romania​—Wọ́n ń sọ ohun tó wà nínú Bíbélì fún ẹnì kan

Ìsọfúnni Ṣókí—Romania

  • 18,944,000—Iye àwọn èèyàn
  • 39,723—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 528—Iye àwọn ìjọ
  • 480—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Baba Kú, àmọ́ Baba Kù

Ka ìtàn ìgbésí ayé Gerrit Lösch, tó jẹ́ ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí.