Ìsọfúnni Ṣókí—Turkey
- 85,957,000—Iye àwọn èèyàn
- 5,692—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 71—Iye àwọn ìjọ
- 15,502—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Tọ́kì
Lọ́dún 2014, wọ́n ṣe àkànṣe ìwàásù kan ní Tọ́kì. Kí nìdí tí wọ́n fi ṣe àkànṣe ìwàásù náà? Kí ló sì yọrí sí?