Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Ukraine

  • Lybokhora, Ukraine​—Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń wàásù ní abúlé kékeré kan

Ìsọfúnni Ṣókí—Ukraine

  • 41,130,000—Iye àwọn èèyàn
  • 109,375—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 1,234—Iye àwọn ìjọ
  • 391—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!

Ó Ti Lé Lọ́dún Kan Tí Ogun Ti Ń Jà ní Ukraine​—Kí Ni Bíbélì Sọ Pé Ọlọ́run Máa Ṣe?

Kẹ́kọ̀ọ́ sí i kó o lè mọ àwọn nǹkan rere tí Ọlọ́run sọ pé òun máa ṣe nínú Bíbélì láti fòpin sí ogun.

Orílẹ̀-èdè Rọ́ṣíà Gbógun Wọ Orílẹ̀-èdè Ukraine​—Ṣé Àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì Ló Ń Ṣẹ?

Tó bá rí bẹ́ẹ̀, ṣé Bíbélì sọ ibi táwọn ohun tó ń ṣẹlẹ̀ yìí máa já sí?

Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!

Ohun Táwọn Ẹlẹ́sìn Ń Ṣe Nípa Ogun Tó Ń Jà Nílẹ̀ Ukraine—Kí Ni Bíbélì Sọ?

Àwọn àlùfáà ṣọ́ọ̀ṣì lórílẹ̀-èdè méjèèjì ń rọ àwọn ọmọ ìjọ wọn pé kí wọ́n ṣe ohun tó yàtọ̀ sí ohun tí Jésù ní káwọn ọmọlẹ́yìn ẹ̀ máa ṣe.