Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

South Africa

  • Stellenbosch, South Africa—Wọ́n ń wàásù fún àgbẹ̀ kan nínú ọgbà àjàrà ní ìgbèríko ìlú Cape Town

  • Bo-Kaap, Cape Town, South Africa—Wọ́n ń wàásù ní ọ̀kan lára àwọn àrọko ìlú

  • Weltevrede, Mpumalanga Province, South Africa​—Wọ́n ń pe obìnrin kan tó jẹ́ ẹ̀yà Ndebele wá sí ìpàdé ní Gbọ̀ngàn Ìjọba

Ìsọfúnni Ṣókí—South Africa

  • 60,605,000—Iye àwọn èèyàn
  • 100,331—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 1,966—Iye àwọn ìjọ
  • 617—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Mo Gbádùn Ayé Mi Gan-an Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà

Ìtàn Ìgbésí Ayé: John Kikot

BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ

Àwọn Ará Ń Gbádùn Tẹlifíṣọ̀n JW Láwọn Ibi Tí Ò Ti Sí Íńtánẹ́ẹ̀tì

Báwo làwọn ará ní Áfíríkà ṣe ń wo ètò tẹlifíṣọ̀n JW láìlo íńtánẹ́ẹ̀tì?