Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? TẸ̀ Ẹ̣́ Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? Wo bí a ṣe máa ń ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ́fẹ̀ẹ́. Máà bínú, ètò tó o fi ń wo fídíò kò ṣiṣẹ́. Wa Fídíò Yìí Jáde O Tún Lè Wo ÌBÉÈRÈ TÁWỌN ÈÈYÀN MÁA Ń BÉÈRÈ Kí Ni Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Kọ́ Àwọn Èèyàn? Ìtumọ̀ Bíbélì èyíkéyìí tó bá wù ẹ́ lo lè lò láti fi kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pẹ̀lú àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà. O sì lè pe gbogbo ìdílé ẹ tàbí kó o pe àwọn ọ̀rẹ́ ẹ wá síbi ìkẹ́kọ̀ọ́ náà. NÍPA WA Ṣé O Fẹ́ Ká Wá Ẹ Wá O lè mọ̀ sí i nípa Bíbélì tàbí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà. ÌPÀDÉ Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba? Wo bó ṣe máa ń rí tá a bá wà nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba. NÍPA WA Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?—Èyí Tó Gùn Bíbélì ń ran ọ̀pọ̀ mílíọ̀nù èèyàn kárí ayé lọ́wọ́ láti rí ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè pàtàkì nípa ìgbésí ayé. Ṣé ìwọ náà á fẹ́ jẹ́ ọ̀kan lára wọn? Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? NÍPA WA Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? Yorùbá Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/502014311/univ/art/502014311_univ_sqr_xl.jpg