MARCH 12, 2021
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ
Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #2
Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí sọ bí nǹkan ṣe ń lọ sí ní Bẹ́tẹ́lì láti fi gbé wa ró, àwọn kan lára ìdílé Bẹ́tẹ́lì náà sọ àwọn ìṣòro tí wọ́n ní àti àwọn ìbùkún tí wọ́n ń gbádùn lásìkò àjàkálẹ̀ àrùn yìí.