Malawi
Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kọ Lẹ́tà Nítorí Àwọn Ará Wa ní Rọ́ṣíà—Láti Màláwì
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Màláwì sọ bó ṣe rí lára wọn nígbà tí wọ́n kọ lẹ́tà sí ìjọba ilẹ̀ Rọ́ṣíà torí àwọn ará wa ní Rọ́ṣíà.
Àwọn Ọmọ Ẹlẹ́rìí Jèhófà Méjì tí Àwọn Aláṣẹ Lé Kúrò Níléèwé Lórí Ọ̀rọ̀ Ẹ̀rí Ọkàn Ti Pa Dà Síléèwé
Torí pé àwọn ọmọ náà kọ̀ láti kọ orin orílẹ̀-èdè ni wọ́n ṣe lé wọn kúrò níléèwé. Àmọ́ àwọn aláṣẹ iléèwé ti ní kí wọ́n pa dà síléèwé báyìí.