Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Mongolia

 

2018-10-15

MONGOLIA

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ti Lómìnira Ẹ̀sìn ní Mòǹgólíà: Ìjọba Pa Dà Forúkọ Ẹ̀sìn Wọn Sílẹ̀ Lábẹ́ Òfin

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ní olú-ìlú orílẹ̀-èdè Mòǹgólíà gba ìwé ẹ̀rí kan látọ̀dọ̀ Àjọ Tó Ń Rí sí Ọ̀rọ̀ Ìlú, pé ìjọba ti pa dà forúkọ ẹ̀sìn wọn sílẹ̀ lábẹ́ òfin.