Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Poland

 

2016-05-04

POLAND

Àwọn Tí Kò Kú sí Àgọ́ Auschwitz Ṣé Ayẹyẹ Àádọ́rin Ọdún Tí Wọ́n ti Wà Lómìnira, Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Wà Lára Àwọn Tí Wọ́n Rántí

Tó bá di January 27, 2015, àwọn aṣojú ìjọba àtàwọn míì máa pé jọ láti ṣayẹyẹ àádọ́rin ọdún tí wọ́n dá àwọn èèyàn sílẹ̀ lómìnira ní àgọ́ ìṣẹ́niníṣẹ̀ẹ́ tí ìjọba Násì ti pa ọ̀pọ̀ èèyàn.